Ìwé Oníwàásù 4:1 BM

1 Mo tún rí i bí àwọn eniyan tí ń ni ẹlòmíràn lára láyé.Wò ó! Omi ń bọ́ lójú àwọn tí à ń ni lára,Kò sì sí ẹnìkan tí yóo tù wọ́n ninu.Ọ̀dọ̀ àwọn tí ń ni wọ́n lára ni agbára kọ̀dí sí,kò sì sí ẹni tí yóo tu àwọn tí à ń ni lára ninu.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 4

Wo Ìwé Oníwàásù 4:1 ni o tọ