12 Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ni eniyan kan lè dojú ìjà kọ,nítorí pé eniyan meji lè gba ara wọn kalẹ̀.Okùn onípọn mẹta kò lè ṣe é já bọ̀rọ̀.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 4
Wo Ìwé Oníwàásù 4:12 ni o tọ