Ìwé Oníwàásù 5:1 BM

1 Ṣọ́ra, nígbà tí o bá lọ sí ilé Ọlọrun, ó sàn kí o lọ máa kẹ́kọ̀ọ́ níbẹ̀ ju pé kí o lọ máa rúbọ bí àwọn aṣiwèrè tí ń ṣe, tí wọn kò sì mọ̀ pé nǹkan burúkú ni àwọn ń ṣe.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 5

Wo Ìwé Oníwàásù 5:1 ni o tọ