Ìwé Oníwàásù 5:19 BM

19 Gbogbo ẹni tí Ọlọrun bá fún ní ọrọ̀ ati ohun ìní, ati agbára láti gbádùn wọn, ati láti gba ìpín rẹ̀ kí ó sì láyọ̀ ninu iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, ẹ̀bùn Ọlọrun ni.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 5

Wo Ìwé Oníwàásù 5:19 ni o tọ