Ìwé Oníwàásù 5:7 BM

7 Nígbà tí àlá bá pọ̀ ọ̀rọ̀ náà yóo pọ̀. Ṣugbọn pataki ni pé, ǹjẹ́ o tilẹ̀ bẹ̀rù Ọlọrun?

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 5

Wo Ìwé Oníwàásù 5:7 ni o tọ