Ìwé Oníwàásù 6:3 BM

3 Bí ẹnìkan bá bí ọgọrun-un ọmọ, tí ó sì gbé ọpọlọpọ ọdún láyé, ṣugbọn tí kò gbádùn àwọn ohun tí ó dára láyé, tí wọn kò sì sin òkú rẹ̀, ọmọ tí a bí lókùú sàn jù ú lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 6

Wo Ìwé Oníwàásù 6:3 ni o tọ