Ìwé Oníwàásù 7:2 BM

2 Ó dára láti lọ sí ilé àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ju ati lọ sí ibi àsè lọ,nítorí pé àwọn alààyè gbọdọ̀ máa rán ara wọn létí péikú ni òpin gbogbo eniyan.Gbogbo alààyè ni wọ́n gbọdọ̀ máa fi èyí sọ́kàn.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7

Wo Ìwé Oníwàásù 7:2 ni o tọ