25 Mo tún pinnu láti kẹ́kọ̀ọ́, láti ṣe ìwádìí, ati láti wá ọgbọ́n, kí n mọ gbogbo nǹkan, ati ibi tí ń bẹ ninu ìwà òmùgọ̀, ati àìlóye tí ó wà ninu ìwà wèrè.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7
Wo Ìwé Oníwàásù 7:25 ni o tọ