Ìwé Oníwàásù 9:5 BM

5 Nítorí alààyè mọ̀ pé òun óo kú, ṣugbọn òkú kò mọ nǹkankan mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní èrè kan mọ́, a kò sì ní ranti wọn mọ́.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 9

Wo Ìwé Oníwàásù 9:5 ni o tọ