Ìwé Oníwàásù 9:9 BM

9 Máa gbádùn ayé pẹlu aya rẹ, olólùfẹ́ rẹ, ní gbogbo ọjọ́ asán tí Ọlọrun fún ọ nílé ayé. Nítorí ìpín tìrẹ nìyí láyé ninu làálàá tí ò ń ṣe.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 9

Wo Ìwé Oníwàásù 9:9 ni o tọ