Joẹli 3:19 BM

19 “Ijipti yóo di aṣálẹ̀;Edomu yóo sì di ẹgàn,nítorí ìwà ipá tí wọ́n hù sí àwọn ará Juda,nítorí wọ́n ti pa àwọn aláìṣẹ̀ ní ilẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Joẹli 3

Wo Joẹli 3:19 ni o tọ