Joẹli 3:20 BM

20 Ṣugbọn àwọn eniyan yóo máa gbé ilẹ̀ Juda títí lae,wọn óo sì máa gbé ìlú Jerusalẹmu láti ìrandíran.

Ka pipe ipin Joẹli 3

Wo Joẹli 3:20 ni o tọ