Nahumu 3:7 BM

7 Ẹnu yóo ya gbogbo àwọn tí ó bá wò ọ́, wọn yóo máawí pé: ‘Ninefe ti di ahoro; ta ni yóo dárò rẹ̀?Níbo ni n óo ti rí olùtùnú fún ọ?’ ”

Ka pipe ipin Nahumu 3

Wo Nahumu 3:7 ni o tọ