Efesu 6:12 BM

12 Nítorí kì í ṣe eniyan ni à ń bá jagun, bíkòṣe àwọn ẹ̀mí burúkú ojú ọ̀run, àwọn aláṣẹ ati àwọn alágbára òkùnkùn ayé yìí.

Ka pipe ipin Efesu 6

Wo Efesu 6:12 ni o tọ