Efesu 6:13 BM

13 Nítorí èyí, ẹ gbé gbogbo ihamọra Ọlọrun wọ̀, kí ẹ lè dìde dúró láti jà nígbà tí ọjọ́ ibi bá dé. Nígbà tí ìjà bá sì dópin, kí ẹ lè wà ní ìdúró.

Ka pipe ipin Efesu 6

Wo Efesu 6:13 ni o tọ