Kọrinti Kinni 1:18 BM

18 Nítorí ọ̀rọ̀ agbelebu Kristi jẹ́ ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ lójú àwọn tí ń ṣègbé. Ṣugbọn lójú àwọn tí à ń gbà là, agbára Ọlọrun ni.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:18 ni o tọ