Kọrinti Kinni 10:2 BM

2 Gbogbo wọn ni wọ́n ṣe ìrìbọmi ninu ìkùukùu ati ninu òkun, kí wọ́n lè di ọmọ ẹ̀yìn Mose.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:2 ni o tọ