Kọrinti Kinni 10:20 BM

20 Rárá o! Ohun tí mò ń sọ ni pé àwọn nǹkan tí àwọn abọ̀rìṣà fi ń rúbọ, ẹ̀mí burúkú ni wọ́n fi ń rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọrun. N kò fẹ́ kí ẹ ní ìdàpọ̀ pẹlu àwọn ẹ̀mí burúkú.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:20 ni o tọ