Kọrinti Kinni 10:28 BM

28 Ṣugbọn bí ẹnìkan bá sọ fun yín pé, “A ti fi oúnjẹ yìí ṣe ìrúbọ,” ẹ má jẹ ẹ́, nítorí ẹni tí ó sọ bẹ́ẹ̀ ati nítorí ẹ̀rí-ọkàn.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:28 ni o tọ