Kọrinti Kinni 10:4 BM

4 Gbogbo wọn ni wọ́n mu omi ẹ̀mí kan náà, nítorí wọ́n mu omi tí ó jáde láti inú òkúta ẹ̀mí tí ó ń tẹ̀lé wọn. Òkúta náà ni Kristi.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:4 ni o tọ