Kọrinti Kinni 11:12 BM

12 Nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé láti ara ọkunrin ni obinrin ti wá, láti inú obinrin ni ọkunrin náà sì ti wá. Ṣugbọn ohun gbogbo ti ọ̀dọ̀ Oluwa wá.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 11

Wo Kọrinti Kinni 11:12 ni o tọ