Kọrinti Kinni 11:18 BM

18 Nítorí, ní ọ̀nà kinni, mo gbọ́ pé nígbà tí ẹ bá péjọ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìjọ, ìyapa a máa wà láàrin yín. Mo gbàgbọ́ pé òtítọ́ wà ninu ìròyìn yìí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 11

Wo Kọrinti Kinni 11:18 ni o tọ