Kọrinti Kinni 12:12 BM

12 Nítorí gẹ́gẹ́ bí ara ti jẹ́ ọ̀kan, tí ó ní ọpọlọpọ ẹ̀yà, bí gbogbo àwọn ẹ̀yà ara ti pọ̀ tó, sibẹ tí ara jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo, bẹ́ẹ̀ ni Kristi rí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 12

Wo Kọrinti Kinni 12:12 ni o tọ