Kọrinti Kinni 12:25 BM

25 kí ó má baà sí ìyapa ninu ara, ṣugbọn kí gbogbo àwọn ẹ̀yà ara lè máa ṣe aájò kan náà fún ara wọn.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 12

Wo Kọrinti Kinni 12:25 ni o tọ