Kọrinti Kinni 12:6 BM

6 Oríṣìíríṣìí iṣẹ́ ni ó wà, ṣugbọn Ọlọrun kan náà ní ń ṣe ohun gbogbo ninu gbogbo eniyan.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 12

Wo Kọrinti Kinni 12:6 ni o tọ