Kọrinti Kinni 12:8 BM

8 Nítorí láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí Mímọ́ ni a ti fún ẹnìkan ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n, a sì fún ẹlòmíràn ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ ìmọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 12

Wo Kọrinti Kinni 12:8 ni o tọ