Kọrinti Kinni 13:13 BM

13 Ní gbolohun kan, àwọn nǹkan mẹta ni ó wà títí lae; igbagbọ, ìrètí, ati ìfẹ́; ṣugbọn èyí tí ó tóbi jù ninu wọn ni ìfẹ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 13

Wo Kọrinti Kinni 13:13 ni o tọ