Kọrinti Kinni 15:12 BM

12 Nígbà tí ó jẹ́ pé, à ń kéde pé Kristi jinde kúrò ninu òkú, báwo ni àwọn kan ninu yín ṣe wá ń wí pé kò sí ajinde òkú?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:12 ni o tọ