Kọrinti Kinni 15:19 BM

19 Tí ó bá jẹ́ pé ninu ayé yìí nìkan ni a ní ìrètí ninu Kristi, àwa ni ẹni tí àwọn eniyan ìbá máa káàánú jùlọ!

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:19 ni o tọ