22 Nítorí bí ó ti jẹ́ pé nípasẹ̀ Adamu ni gbogbo eniyan ṣe kú, bẹ́ẹ̀ náà ni ó sì jẹ́ pé nípasẹ̀ Kristi ni a sọ gbogbo eniyan di alààyè.
Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15
Wo Kọrinti Kinni 15:22 ni o tọ