Kọrinti Kinni 15:24 BM

24 Lẹ́yìn náà ni òpin yóo dé, lẹ́yìn tí ó bá ti dá ìjọba pada fún Ọlọrun Baba, tí ó sì ti pa gbogbo àṣẹ, ọlá ati agbára run.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:24 ni o tọ