Kọrinti Kinni 15:29 BM

29 Ó tún ku nǹkankan! Nítorí kí ni àwọn kan ṣe ń ṣe ìrìbọmi nítorí àwọn tí ó kú? Bí a kò bá ní jí àwọn òkú dìde, kí ni ìdí rẹ̀ tí wọ́n fi ń ṣe ìrìbọmi nítorí wọn?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:29 ni o tọ