Kọrinti Kinni 15:32 BM

32 Bí mo bá tìtorí iyì eniyan bá ẹranko jà ní Efesu, anfaani wo ni ó ṣe fún mi? Bí a kò bá jí àwọn òkú dìde, bí wọ́n ti máa ń wí, wọn á ní:“Ẹ jẹ́ kí á máa jẹ, kí á máa mu,nítorí ọ̀la ni a óo kú.”

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:32 ni o tọ