Kọrinti Kinni 15:9 BM

9 Nítorí èmi ni mo kéré jùlọ ninu àwọn aposteli. N kò tilẹ̀ yẹ ní ẹni tí wọn ìbá máa pè ní aposteli, nítorí pé mo ṣe inúnibíni sí ìjọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:9 ni o tọ