Kọrinti Kinni 16:1 BM

1 Nípa ti ìtọrẹ tí ẹ̀ ń ṣe fún àwọn eniyan Ọlọrun, bí mo ti ṣe ètò pẹlu àwọn ìjọ Galatia, bẹ́ẹ̀ gan-an ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 16

Wo Kọrinti Kinni 16:1 ni o tọ