Kọrinti Kinni 16:17 BM

17 Inú mi dùn nígbà tí Stefana ati Fotunatu ati Akaiku dé, nítorí dídé tí wọ́n dé dí àlàfo tí ó ṣí sílẹ̀ nítorí àìsí yín lọ́dọ̀ wa.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 16

Wo Kọrinti Kinni 16:17 ni o tọ