Kọrinti Kinni 16:3 BM

3 Nígbà tí mo bá dé, n óo kọ ìwé lé àwọn tí ẹ bá yàn lọ́wọ́, n óo rán wọn láti mú ọrẹ yín lọ sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 16

Wo Kọrinti Kinni 16:3 ni o tọ