Kọrinti Kinni 2:13 BM

13 Ohun tí à ń sọ kì í ṣe ohun tí eniyan fi ọ̀rọ̀ ọgbọ́n kọ́ wa. Ẹ̀mí ni ó kọ́ wa bí a ti ń túmọ̀ nǹkan ti ẹ̀mí, fún àwọn tí wọ́n ní Ẹ̀mí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 2

Wo Kọrinti Kinni 2:13 ni o tọ