Kọrinti Kinni 3:19 BM

19 Nítorí agọ̀ ni ọgbọ́n ayé yìí lójú Ọlọrun. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Ẹni tí ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n ninu àrékérekè wọn.”

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 3

Wo Kọrinti Kinni 3:19 ni o tọ