Kọrinti Kinni 4:15 BM

15 Nítorí pé, ẹ̀ báà ní ẹgbẹrun àwọn olùtọ́ ninu Kristi, ẹ kò ní ju ẹyọ baba kan lọ. Nítorí ninu Kristi Jesu, èmi ni mo bi yín nípa ọ̀rọ̀ ìyìn rere.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 4

Wo Kọrinti Kinni 4:15 ni o tọ