Kọrinti Kinni 4:19 BM

19 Ṣugbọn mò ń bọ̀ láìpẹ́, bí Oluwa bá fẹ́. N óo wá mọ agbára tí àwọn tí wọn ń gbéraga ní nígbà náà, yàtọ̀ sí ọ̀rọ̀ ẹnu wọn lásán.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 4

Wo Kọrinti Kinni 4:19 ni o tọ