Kọrinti Kinni 4:9 BM

9 Nítorí mo rò pé Ọlọrun ti fi àwa òjíṣẹ́ hàn ní ìkẹyìn bí àwọn tí a dá lẹ́bi ikú, nítorí a ti di ẹni tí gbogbo ayé fi ń ṣe ìran wò: ati àwọn angẹli, ati àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 4

Wo Kọrinti Kinni 4:9 ni o tọ