Kọrinti Kinni 6:4 BM

4 Bí ẹ bá ní ẹ̀sùn nípa nǹkan ti ayé, kí ló dé ti ẹ fi ń pe àwọn alaigbagbọ tí kò lẹ́nu ninu ìjọ láti máa jókòó lórí ọ̀rọ̀ yín?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 6

Wo Kọrinti Kinni 6:4 ni o tọ