Kọrinti Kinni 7:17 BM

17 Kí olukuluku máa gbé ìgbé-ayé rẹ̀ bí Oluwa ti yàn án fún un, kí ó sì wà ní ipò tí ó wà nígbà tí Ọlọrun fi pè é láti di onigbagbọ. Bẹ́ẹ̀ ni mò ń fi kọ́ gbogbo àwọn ìjọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:17 ni o tọ