Kọrinti Kinni 7:25 BM

25 N kò ní àṣẹ kan láti ọ̀dọ̀ Oluwa láti pa fún àwọn wundia. Ṣugbọn mò ń sọ ohun tí mo rò gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Oluwa ti ṣàánú fún, tí eniyan sì lè gbẹ́kẹ̀lé.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:25 ni o tọ