Kọrinti Kinni 7:4 BM

4 Kì í ṣe iyawo ni ó ni ara rẹ̀, ọkọ rẹ̀ ni ó ni í; bákan náà ni ọkọ, òun náà kò dá ara rẹ̀ ni, iyawo rẹ̀ ni ó ni í.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:4 ni o tọ