Kọrinti Kinni 7:9 BM

9 Ṣugbọn bí wọn kò bá lè mú ara dúró, wọ́n níláti gbeyawo. Nítorí ó sàn kí wọ́n gbeyawo jù pé kí ara wọn máa gbóná nítorí èrò ìbálòpọ̀ ọkunrin ati obinrin.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:9 ni o tọ