Kọrinti Kinni 8:4 BM

4 Nítorí náà nípa oúnjẹ tí a fi rúbọ fún oriṣa, a mọ̀ pé oriṣa kò jẹ́ nǹkankan ninu ayé. Ati pé kò sí Ọlọrun mìíràn àfi ọ̀kan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 8

Wo Kọrinti Kinni 8:4 ni o tọ