Kọrinti Kinni 9:23 BM

23 Èmi a máa ṣe gbogbo nǹkan wọnyi nítorí ti ìyìn rere, kí n lè ní ìpín ninu ibukun rẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:23 ni o tọ