Kọrinti Kinni 9:25 BM

25 Nítorí gbogbo àwọn tí ń sáré ìje a máa kó ara wọn ní ìjánu. Wọ́n ń ṣe èyí kí wọ́n lè gba adé tí yóo bàjẹ́. Ṣugbọn adé tí kò lè bàjẹ́ ni tiwa.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:25 ni o tọ